1
Saamu 96:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí títóbi ní OLúWA ẹni tí ìyìn tọ́ sí; òun ní o yẹ kí a bẹ̀rù ju gbogbo òrìṣà lọ
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 96:4
2
Saamu 96:2
Ẹ kọrin sí OLúWA, yin orúkọ rẹ̀ ẹ sọ ti ìgbàlà rẹ̀ ní ọjọ́ dé ọjọ́
Ṣàwárí Saamu 96:2
3
Saamu 96:1
Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA: Ẹ kọrin sí OLúWA gbogbo ayé.
Ṣàwárí Saamu 96:1
4
Saamu 96:3
Ẹ sọ ti ògo rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè àti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrín gbogbo ènìyàn.
Ṣàwárí Saamu 96:3
5
Saamu 96:9
Ẹ máa sin OLúWA nínú ẹwà ìwà mímọ́ rẹ̀; ẹ wárìrì níwájú rẹ̀ gbogbo ayé.
Ṣàwárí Saamu 96:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò