1
Saamu 97:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ kí gbogbo àwọn tí ó fẹ́ OLúWA, kórìíra ibi, ó pa ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́ ó gbà wọ́n ní ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 97:10
2
Saamu 97:12
Ẹ yọ̀ nínú OLúWA, ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ olódodo, kí ẹ sì yin orúkọ rẹ̀ mímọ́.
Ṣàwárí Saamu 97:12
3
Saamu 97:11
Ìmọ́lẹ̀ tàn sórí àwọn olódodo àti ayọ̀ nínú àlàyé ọkàn
Ṣàwárí Saamu 97:11
4
Saamu 97:9
Nítorí pé ìwọ, OLúWA, ni ó ga ju gbogbo ayé lọ ìwọ ni ó ga ju gbogbo òrìṣà lọ.
Ṣàwárí Saamu 97:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò