Saamu 97:10

Saamu 97:10 YCB

Jẹ kí gbogbo àwọn tí ó fẹ́ OLúWA, kórìíra ibi, ó pa ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́ ó gbà wọ́n ní ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú.