1
Orin Solomoni 4:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Gbogbo ara rẹ jẹ́ kìkì ẹwà, olólùfẹ́ mi; kò sì ṣí àbàwọ́n lára rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Orin Solomoni 4:7
2
Orin Solomoni 4:9
Ìwọ ti gba ọkàn mi, arábìnrin mi, ìyàwó mi; ìwọ ti gba ọkàn mi pẹ̀lú ìwò ẹ̀ẹ̀kan ojú rẹ, pẹ̀lú ọ̀kan nínú ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ
Ṣàwárí Orin Solomoni 4:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò