1
Orin Solomoni 3:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ní orí ibùsùn mi ní òru mo wá ẹni tí ọkàn mí fẹ́; mo wá a, ṣùgbọ́n èmi kò rí i.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Orin Solomoni 3:1
2
Orin Solomoni 3:2
Èmi yóò dìde nísinsin yìí, èmi yóò sì rìn lọ káàkiri ìlú, ní àwọn òpópónà àti ní àwọn gbangba òde; Èmi yóò wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́. Bẹ́ẹ̀ ni mo wá a ṣùgbọ́n èmi kò rí i.
Ṣàwárí Orin Solomoni 3:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò