1
Sefaniah 1:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Bẹ́ẹ̀ ni fàdákà tàbí wúrà wọn kì yóò sì le gbà wọ́n là ní ọjọ́ ìbínú OLúWA.” Ṣùgbọ́n gbogbo ayé ni a ó fi iná ìjowú rẹ̀ parun, nítorí òun yóò fi ìyára fi òpin sí gbogbo àwọn tí ń gbé ní ilẹ̀ ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Sefaniah 1:18
2
Sefaniah 1:14
“Ọjọ́ ńlá OLúWA kù sí dẹ̀dẹ̀, ó kù sí dẹ̀dẹ̀ ó sì ń yára bọ̀ kánkán. Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, ohùn ẹkún àwọn alágbára ní ọjọ́ OLúWA yóò korò púpọ̀
Ṣàwárí Sefaniah 1:14
3
Sefaniah 1:7
Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú OLúWA Olódùmarè, nítorí tí ọjọ́ OLúWA kù sí dẹ̀dẹ̀. OLúWA ti pèsè ẹbọ kan sílẹ̀, ó sì ti ya àwọn alápèjẹ rẹ̀ sí mímọ́.
Ṣàwárí Sefaniah 1:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò