ÀWỌN ỌBA KINNI 17:5

ÀWỌN ỌBA KINNI 17:5 YCE

Elija bá lọ, ó ṣe bí OLUWA ti wí, ó sì ń gbé ẹ̀bá odò Keriti, ní ìhà ìlà oòrùn odò Jọdani.