ÀWỌN ỌBA KINNI 17:6

ÀWỌN ỌBA KINNI 17:6 YCE

Àwọn ẹyẹ ìwò ń gbé oúnjẹ ati ẹran wá fún un ní ojoojumọ, ní àràárọ̀ ati ní ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́, ó sì ń mu omi odò náà.