ÀWỌN ỌBA KINNI 17:9

ÀWỌN ỌBA KINNI 17:9 YCE

“Dìde nisinsinyii, kí o lọ sí ìlú Sarefati, ní agbègbè Sidoni, kí o sì máa gbé ibẹ̀. Mo ti pàṣẹ fún opó kan níbẹ̀ láti máa fún ọ ní oúnjẹ.”