ÀWỌN ỌBA KINNI 18:39

ÀWỌN ỌBA KINNI 18:39 YCE

Nígbà tí àwọn eniyan náà rí i, wọ́n dojúbolẹ̀, wọ́n wí pé, “OLUWA ni Ọlọrun! OLUWA ni Ọlọrun!”