ÀWỌN ỌBA KINNI 19:2

ÀWỌN ỌBA KINNI 19:2 YCE

Jesebẹli bá rán oníṣẹ́ kan sí Elija pẹlu ìbúra pé, “Kí àwọn oriṣa pa mí, bí n kò bá pa ọ́ ní ìwòyí ọ̀la, bí o ti pa àwọn wolii Baali.”