ÀWỌN ỌBA KINNI 19:20

ÀWỌN ỌBA KINNI 19:20 YCE

Eliṣa fi àjàgà mààlúù rẹ̀ sílẹ̀, ó sáré tẹ̀lé Elija, o wí fún un pé, “Jẹ́ kí n lọ dágbére fún baba ati ìyá mi, kí n fi ẹnu kò wọ́n lẹ́nu, kí n tó máa tẹ̀lé ọ.” Elija dá a lóhùn pé, “Pada lọ, àbí, kí ni mo ṣe fún ọ?”