ÀWỌN ỌBA KINNI 19:5

ÀWỌN ỌBA KINNI 19:5 YCE

Ó dùbúlẹ̀ lábẹ́ igi náà, ó sì sùn. Lójijì, angẹli kan fi ọwọ́ kàn án, ó sì wí fún un pé, “Dìde kí o jẹun.”