ÀWỌN ỌBA KINNI 19:8

ÀWỌN ỌBA KINNI 19:8 YCE

Elija dìde, ó jẹun, ó sì tún mu omi. Oúnjẹ náà sì fún un ní agbára láti rìn fún ogoji ọjọ́ tọ̀sán-tòru títí tí ó fi dé orí òkè Horebu, òkè Ọlọrun.