I. A. Ọba 19:8
I. A. Ọba 19:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si dide, o si jẹ, o mu, o si lọ li agbara onjẹ yi li ogoji ọsan ati ogoji oru si Horebu, oke Ọlọrun.