I. A. Ọba 19:8

I. A. Ọba 19:8 YBCV

O si dide, o si jẹ, o mu, o si lọ li agbara onjẹ yi li ogoji ọsan ati ogoji oru si Horebu, oke Ọlọrun.