ÀWỌN ỌBA KEJI 4:6

ÀWỌN ỌBA KEJI 4:6 YCE

Nígbà tí gbogbo àwọn ìkòkò náà kún, obinrin náà bèèrè bóyá ìkòkò kù, àwọn ọmọ rẹ̀ sì dáhùn pé ó ti tán, òróró náà sì dá.