II. A. Ọba 4:6
II. A. Ọba 4:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si ṣe, nigbati awọn ikòko kún, o wi fun ọmọ rẹ̀ pe, Tun mu ikòko kan fun mi wá. On si wi fun u pe, Kò si ikòko kan mọ. Ororo na si da.