ÀWỌN ỌBA KEJI 6:6

ÀWỌN ỌBA KEJI 6:6 YCE

Eliṣa bèèrè pé, “Níbo ni ó bọ́ sí?” Ọkunrin náà sì fi ibẹ̀ hàn án. Eliṣa gé igi kan, ó jù ú sinu omi, irin àáké náà sì léfòó lójú omi.