II. A. Ọba 6:6
II. A. Ọba 6:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Enia Ọlọrun si wipe, Nibo li o bọ́ si? O si fi ibẹ hàn a. On si ké igi kan, o si sọ́ ọ sinu rẹ̀; irin na si fó soke.