SAMUẸLI KEJI 12:13

SAMUẸLI KEJI 12:13 YCE

Dafidi bá dáhùn pé, “Mo ti ṣẹ̀ sí OLUWA.” Natani dá a lóhùn pé, “OLUWA ti dáríjì ọ́, o kò sì ní kú.