2 Samuẹli 12:13

2 Samuẹli 12:13 YCB

Dafidi sì wí fún Natani pé, “Èmi ṣẹ̀ sí OLúWA!” Natani sì wí fún Dafidi pé, “OLúWA pẹ̀lú sì ti mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò; ìwọ kì yóò kú.