ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 10:43

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 10:43 YCE

Òun ni gbogbo àwọn wolii ń jẹ́rìí sí, tí wọ́n sọ pé gbogbo ẹni tí ó bá gbà á gbọ́ yóo ní ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ní orúkọ rẹ̀.”