ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:29

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:29 YCE

Nígbà tí a jẹ́ ọmọ Ọlọrun, kò yẹ kí á rò pé Ọlọrun dàbí ère wúrà, tabi fadaka, tabi òkúta, ère tí oníṣẹ́ ọnà ṣe pẹlu ọgbọ́n ati èrò eniyan.