ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:10

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:10 YCE

Nítorí n óo wà pẹlu rẹ. Kò sí ẹni tí yóo fọwọ́ kàn ọ́ láti ṣe ọ́ níbi. Nítorí mo ní eniyan pupọ ninu ìlú yìí.”