ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:9

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:9 YCE

Ní alẹ́ ọjọ́ kan, Paulu rí ìran kan. Ninu ìran náà Oluwa sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, máa waasu, má dákẹ́.