ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 19:6

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 19:6 YCE

Nígbà tí Paulu gbé ọwọ́ lé wọn, Ẹ̀mí Mímọ́ bà lé wọn, wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí fi èdè mìíràn sọ̀rọ̀, wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀.