ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:34

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:34 YCE

Mo ti rí gbogbo ìrora tí àwọn eniyan mi ń jẹ ní Ijipti. Mo ti gbọ́ ìkérora wọn, mo sì ṣetán láti yọ wọ́n. Ó yá nisinsinyii. N óo rán ọ lọ sí Ijipti.’