ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 9:15

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 9:15 YCE

Oluwa sọ fún un pé, “Lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, nítorí mo ti yàn án láti mú orúkọ mi lọ siwaju àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ati àwọn ọba wọn ati àwọn ọmọ Israẹli.