ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:2-3

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:2-3 YCE

Asán ninu asán, bí ọ̀jọ̀gbọ́n ti wí, asán ninu asán, gbogbo rẹ̀ asán ni. Èrè kí ni eniyan ń jẹ ninu gbogbo làálàá rẹ̀, tí ó ń ṣe nílé ayé?