ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:1

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:1 YCE

Bí òkú eṣinṣin ṣe lè ba òórùn turari jẹ́; bẹ́ẹ̀ ni ìwà òmùgọ̀ kékeré lè ba ọgbọ́n ńlá ati iyì jẹ́.