ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:4

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:4 YCE

Bí aláṣẹ bá ń bínú sí ọ, má ṣe torí rẹ̀ kúrò ní ìdí iṣẹ́ rẹ, ìtẹríba lè mú kí wọn dárí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó bá tóbi jini.