ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:14

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 2:14 YCE

Ọlọ́gbọ́n ní ojú lágbárí, ṣugbọn ninu òkùnkùn ni òmùgọ̀ ń rìn. Sibẹ mo rí i pé, nǹkankan náà ni ó ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.