ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:6

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 4:6 YCE

Ó sàn kí eniyan ní nǹkan díẹ̀ pẹlu ìbàlẹ̀ àyà ju pé kí ó ní ọpọlọpọ, pẹlu làálàá ati ìmúlẹ̀mófo lọ.