ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 6:10

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 6:10 YCE

Ohunkohun tí ó bá ti wà, ó ti ní orúkọ tẹ́lẹ̀, a sì ti mọ ẹ̀dá eniyan, pé eniyan kò lè bá ẹni tí ó lágbára jù ú lọ jà.