ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 6:9

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 6:9 YCE

Ó sàn kí ojú ẹni rí nǹkan, ju kí á máa fi ọkàn lépa rẹ̀ lọ. Asán ati ìmúlẹ̀mófo ni èyí pẹlu.