ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:12

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:12 YCE

Bí ẹlẹ́ṣẹ̀ tilẹ̀ ṣe ibi ní ọpọlọpọ ìgbà tí ọjọ́ rẹ̀ sì gùn, sibẹsibẹ mo mọ̀ pé yóo dára fún àwọn tí ó bẹ̀rù Ọlọrun.