ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:10

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:10 YCE

Ohunkohun tí o bá ti dáwọ́ lé, fi gbogbo agbára rẹ ṣe é nítorí, kò sí iṣẹ́, tabi èrò, tabi ìmọ̀, tabi ọgbọ́n, ní isà òkú tí ò ń lọ.