ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:18

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:18 YCE

Ọgbọ́n dára ju ohun ìjà ogun lọ, ṣugbọn ẹlẹ́ṣẹ̀ kanṣoṣo a máa ba nǹkan ribiribi jẹ́.