ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:9

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:9 YCE

Máa gbádùn ayé pẹlu aya rẹ, olólùfẹ́ rẹ, ní gbogbo ọjọ́ asán tí Ọlọrun fún ọ nílé ayé. Nítorí ìpín tìrẹ nìyí láyé ninu làálàá tí ò ń ṣe.