AISAYA 43:19

AISAYA 43:19 YCE

Ẹ wò ó! Mò ń ṣe nǹkan titun ó ti yọ jáde nisinsinyii, àbí ẹ kò ṣe akiyesi rẹ̀? N óo la ọ̀nà ninu aginjù, n óo sì mú kí omi máa ṣàn ninu aṣálẹ̀.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 43:19

AISAYA 43:19 - Ẹ wò ó! Mò ń ṣe nǹkan titun
ó ti yọ jáde nisinsinyii,
àbí ẹ kò ṣe akiyesi rẹ̀?
N óo la ọ̀nà ninu aginjù,
n óo sì mú kí omi máa ṣàn ninu aṣálẹ̀.