AISAYA 43:2

AISAYA 43:2 YCE

Nígbà tí o bá ń la ibú omi kọjá, n óo wà pẹlu rẹ; nígbà tí o bá la odò ńlá kọjá, kò ní bò ọ́ mọ́lẹ̀, nígbà tí o bá ń kọjá ninu iná, kò ní jó ọ. Ahọ́n iná kò ní jó ọ run.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 43:2

AISAYA 43:2 - Nígbà tí o bá ń la ibú omi kọjá,
n óo wà pẹlu rẹ;
nígbà tí o bá la odò ńlá kọjá,
kò ní bò ọ́ mọ́lẹ̀,
nígbà tí o bá ń kọjá ninu iná, kò ní jó ọ.
Ahọ́n iná kò ní jó ọ run.