AISAYA 44:8

AISAYA 44:8 YCE

Má bẹ̀rù, má sì fòyà. Ṣebí mo ti sọ fún ọ tipẹ́, mo ti kéde rẹ̀, ìwọ sì ni ẹlẹ́rìí mi: Ǹjẹ́ Ọlọrun mìíràn wà lẹ́yìn mi? Kò tún sí àpáta kan mọ́, n kò mọ ọ̀kan kan.”