AISAYA 5:20

AISAYA 5:20 YCE

Àwọn tí ń pe ibi ní ire gbé; tí wọn ń pe ire ní ibi! Àwọn tí wọn ń fi òkùnkùn ṣe ìmọ́lẹ̀, tí wọn sì fi ìmọ́lẹ̀ ṣe òkùnkùn! Tí wọ́n fi ìkorò ṣe adùn, tí wọ́n sì fi adùn ṣe ìkorò.