AISAYA 53:5

AISAYA 53:5 YCE

Ṣugbọn wọ́n ṣá a lọ́gbẹ́ nítorí àìdára wa, wọ́n pa á lára nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa; ìyà tí wọ́n fi jẹ ẹ́ ni ó fún wa ní alaafia, nínà tí a nà án ni ó mú wa lára dá.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 53:5

AISAYA 53:5 - Ṣugbọn wọ́n ṣá a lọ́gbẹ́ nítorí àìdára wa,
wọ́n pa á lára nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa;
ìyà tí wọ́n fi jẹ ẹ́ ni ó fún wa ní alaafia,
nínà tí a nà án ni ó mú wa lára dá.