AISAYA 55:12

AISAYA 55:12 YCE

“Nítorí tayọ̀tayọ̀ ni ẹ óo fi máa jáde ní Babiloni, alaafia ni wọ́n óo fi máa sìn yín sọ́nà, òkè ńlá ati kéékèèké yóo máa kọrin níwájú yín. Gbogbo igi inú igbó yóo sì máa pàtẹ́wọ́