JEREMAYA 4:18

JEREMAYA 4:18 YCE

Ìrìn ẹsẹ̀ rẹ ati ìwà rẹ ni ó mú kí àwọn nǹkan wọnyi dé bá ọ. Ìjìyà rẹ nìyí, ó sì korò; ó ti dé oókan àyà rẹ.