LUKU 2:13-14

LUKU 2:13-14 YCE

Lójijì ọpọlọpọ àwọn ogun ọ̀run yọ pẹlu angẹli náà, wọ́n ń yin Ọlọrun pé, “Ògo fún Ọlọrun lókè ọ̀run, alaafia ní ayé fún àwọn tí inú Ọlọrun dùn sí.”

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún LUKU 2:13-14

LUKU 2:13-14 - Lójijì ọpọlọpọ àwọn ogun ọ̀run yọ pẹlu angẹli náà, wọ́n ń yin Ọlọrun pé,
“Ògo fún Ọlọrun lókè ọ̀run,
alaafia ní ayé fún àwọn tí inú Ọlọrun dùn sí.”