Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

ÌWÉ ÒWE 1:1-4

ÌWÉ ÒWE 1:1-4 YCE

Àwọn òwe tí Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli pa, kí àwọn eniyan lè ní ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́, kí òye ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lè yé wọn, láti gba ẹ̀kọ́, tí yóo kọ́ni lọ́gbọ́n, òdodo, ẹ̀tọ́ ati àìṣojúṣàájú, láti kọ́ onírẹ̀lẹ̀ lọ́gbọ́n, kí á sì fi ìmọ̀ ati làákàyè fún ọ̀dọ́,