ÌWÉ ÒWE 14:16

ÌWÉ ÒWE 14:16 YCE

Ọlọ́gbọ́n a máa ṣọ́ra, a sì máa sá fún ibi, ṣugbọn òmùgọ̀ kì í rọra ṣe, kì í sì í bìkítà.